Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
stringlengths
43
45
text
stringlengths
2
183
duration_sec
float64
0.06
21
source_parquet
stringclasses
99 values
source_index
int64
0
2.09k
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000013.wav
Mo n yan ipele aladun miiran ti awọn kuki chirún chocolate.
4.62
train-00000-of-00099.parquet
13
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000020.wav
Ọkò òfurufú kìí balẹ̀ sórí koríko.
2.4
train-00000-of-00099.parquet
20
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000026.wav
Àwọn gbajugbaja náà fẹ dé
1.8
train-00000-of-00099.parquet
26
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000043.wav
Ègbè àjè jè ègbè áwòn óbirin
2.22
train-00000-of-00099.parquet
43
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000046.wav
Bàbá àgbà ló ni oògùn ojú náà
2.22
train-00000-of-00099.parquet
46
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000055.wav
Ìyá Bọ́lá máa ń sun ẹran wọn.
2.52
train-00000-of-00099.parquet
55
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000093.wav
Ní àtijọ́, kò wọ́pọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti lọ sí ilé ìwé lẹ́yìn ọdún mẹ́rìnlá
6.12
train-00000-of-00099.parquet
93
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000126.wav
Ṣé wọ́n ti dín ṣíńṣíìn tán?
1.8
train-00000-of-00099.parquet
126
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000156.wav
Mo kí ẹ̀gbọ́n obìnrin kú ayọ̀ ọmọ
3
train-00000-of-00099.parquet
156
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000166.wav
Bísí bọ ọwọ́ díìnì ilé ìwé ní àná
3.18
train-00000-of-00099.parquet
166
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000170.wav
Àmúga-ìjẹun jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun ìjẹun.
3.24
train-00000-of-00099.parquet
170
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000174.wav
Mo rí bàbá ọkọ re lánàá
1.98
train-00000-of-00099.parquet
174
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000185.wav
Ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ sí san owó oṣù àwọn olùkọ́
2.58
train-00000-of-00099.parquet
185
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000192.wav
Ọtí wáìnì ni mo máa mu bí mo dé ilé ọtí
3.12
train-00000-of-00099.parquet
192
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000216.wav
Ó máà ń lo klípà oníná míràn láti pàrọ̀ tí tẹ́lẹ̀.
6.42
train-00000-of-00099.parquet
216
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000230.wav
Àwọn ọmọ náà ń ta ọ̀gẹ̀dẹ̀ ní ọjà Èkó.
3.42
train-00000-of-00099.parquet
230
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000231.wav
Ọjọ kini, oṣù kini ni ìbẹ̀rẹ̀ ọdún tuntun
3.18
train-00000-of-00099.parquet
231
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000240.wav
Bẹ́ẹ̀ni, mo se ẹja tí o ti rọ̀ náà lánàá.
2.94
train-00000-of-00099.parquet
240
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000287.wav
Alugongo níi polongo ikú oba.
3.18
train-00000-of-00099.parquet
287
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000296.wav
Iṣu tí ó wọ́pọ̀ ní iṣu funfun
2.82
train-00000-of-00099.parquet
296
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000315.wav
Sé o fẹ́ràn ẹ̀wà òtílí náà
1.92
train-00000-of-00099.parquet
315
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000318.wav
Òyẹ kí wón máa ta oúnjẹ ìbílẹ̀ ní ilé oúnjẹ náà.
4.08
train-00000-of-00099.parquet
318
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000352.wav
Ó kán dígí ẹ̀gbẹ́ ọkọ̀ rẹ̀.
2.82
train-00000-of-00099.parquet
352
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000364.wav
A tú Ìrọ̀rí kékèké náà ká sí gbogbo ibi.
4.56
train-00000-of-00099.parquet
364
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000367.wav
Ǹjẹ́ ọkùnrin nìkan ló ń ṣe iṣẹ́ adájọ́?
2.4
train-00000-of-00099.parquet
367
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000373.wav
Ènìyàn kò gbọ́dọ̀ gba ẹ̀mí ara rẹ̀
2.46
train-00000-of-00099.parquet
373
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000378.wav
Dẹ́kùn àṣìkọ sípẹ́lì àwọn ọjọ́ ọ̀sẹ̀ Lárúbáwá.
4.26
train-00000-of-00099.parquet
378
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000386.wav
Gbénga nìkan ni kì í lọ ṣọ́ọ̀ṣì mọ́ nínú ilé yẹn
3.66
train-00000-of-00099.parquet
386
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000411.wav
Atupa atupa iwọntunwọnsi jẹ ọkan ninu awọn ohun elo inu yara
5.4
train-00000-of-00099.parquet
411
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000415.wav
ṣe o n fun ní Òdòdó tó rẹwà ?
2.76
train-00000-of-00099.parquet
415
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000427.wav
Ṣé ọlọ́jàá tí o lò lánàá dá ìgbẹ́ tí ò ń yà dúró.
4.5
train-00000-of-00099.parquet
427
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000439.wav
Sé o ti ra àjá yen?
2.04
train-00000-of-00099.parquet
439
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000446.wav
Kínní ẹsìn ìgbàgbọ rẹ?
1.74
train-00000-of-00099.parquet
446
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000454.wav
Wọn ó ra ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọti fun igbeyawo na
2.7
train-00000-of-00099.parquet
454
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000465.wav
Njé mo le ri abó alámo ra?
3.06
train-00000-of-00099.parquet
465
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000467.wav
ẹgbẹ̀rún lé ọ̀kan dín ogójì lé ní ẹgbẹ́ta ò ṣé é pín sí méjì.
6.24
train-00000-of-00099.parquet
467
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000471.wav
njé ọmọ yen sìn mú ọyàn ?
0.12
train-00000-of-00099.parquet
471
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000472.wav
Major general ni bàbá mi.
2.4
train-00000-of-00099.parquet
472
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000478.wav
Níbo ni ilé ìwẹ̀ àtijọ́ má ń wà?
2.58
train-00000-of-00099.parquet
478
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000484.wav
Ìgbéyàwó ni ìlaná tí aṣa ní a n pẹ ní ìgbéyàwó aṣa
4.2
train-00000-of-00099.parquet
484
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000499.wav
Gbé kòmpútá yèn lò lòlá
2.1
train-00000-of-00099.parquet
499
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000527.wav
Àwọn Yorùbá máa ń sọ pé ẹni tó bá kẹ́yìn ló rupòó
3.72
train-00000-of-00099.parquet
527
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000543.wav
Àwọn àgbà ló máa n sọ òwe ni aye ode oni
3.12
train-00000-of-00099.parquet
543
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000566.wav
Ó dáa, ìlù náà ti wà báyìí
1.5
train-00000-of-00099.parquet
566
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000583.wav
Ìgbéyàwó láàárín ọkùnrin àti ọkùnrin tàbí obìnrin àti obìnrin lòdì sí òfin ní Nàìjíríà.
7.68
train-00000-of-00099.parquet
583
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000586.wav
Wọn ò mọ oúnjẹ tí wọ́n máa bèrè fún.
3.18
train-00000-of-00099.parquet
586
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000604.wav
iṣẹ́ àdirẹ wọ́pọ̀ láàrin àwọn ará ìlú Ẹ̀gbá
4.92
train-00000-of-00099.parquet
604
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000606.wav
Rárá, mi ò rí àsá náà
2.46
train-00000-of-00099.parquet
606
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000647.wav
Ata ni a fi n sebẹ̀
4.62
train-00000-of-00099.parquet
647
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000659.wav
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn obìnrin ló máa ń wọ yẹtí
2.88
train-00000-of-00099.parquet
659
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000663.wav
A n wọ aṣọ to rẹwà láti buyi kún ni
3.12
train-00000-of-00099.parquet
663
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000685.wav
Oko jẹ ohun elo akọkọ fun sisọ ile ni awọn iṣe ogbin ibile
4.5
train-00000-of-00099.parquet
685
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000687.wav
Ma se ṣe eṣe ìbálòpọ̀ ẹbí!
2.22
train-00000-of-00099.parquet
687
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000689.wav
Máa gbá tennisi tí a bá ti dé ọgbà ìṣẹ̀rẹ́.
3.96
train-00000-of-00099.parquet
689
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000697.wav
Òpòlopò àwon olósèlú ni yio kówó orílẹ̀dè náà je
3.18
train-00000-of-00099.parquet
697
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000712.wav
Agbójú lógún fi ará rẹ fun oṣi ta. Ṣugbọn Atunramu kii n tẹ bọrọ.
5.16
train-00000-of-00099.parquet
712
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000718.wav
Títí àti Adé ń fẹ́ ara wọn.
2.46
train-00000-of-00099.parquet
718
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000719.wav
Mo fẹ́ ra qùránì tuntun
2.82
train-00000-of-00099.parquet
719
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000725.wav
Awọn ayé fún idàgbàsókè ọjọ́gbọ́n, ìkẹ́kọ̀, àti idàgbàsókè ọ̀gbọn ni a fún ni nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ awọn ọ̀fíìsì Nàìjíríà.
10.68
train-00000-of-00099.parquet
725
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000730.wav
Ẹni tí ẹ bá jọ ní bàbá kan náà ni à ń pè ní ọbàkan
3
train-00000-of-00099.parquet
730
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000746.wav
Àjọ̀dún ọjọ́ àṣà Akin dùn gan-an.
2.58
train-00000-of-00099.parquet
746
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000761.wav
Irinṣẹ́ to ń ka owó ẹyọ máa ń lo ìwọ̀n.
2.22
train-00000-of-00099.parquet
761
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000771.wav
Ìgbà wo ni o ra àwọn spaghetti yi?
3.36
train-00000-of-00099.parquet
771
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000779.wav
Òwe "Apẹ́kótójẹ kò ní jẹ̀'bàjẹ́" jẹ́ ọ̀nà tí a fí ń kọ́ sùúrù.
8.52
train-00000-of-00099.parquet
779
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000789.wav
Bẹ́ẹ̀ni, àwọn èèyàn ṣì ń gbé inú GRA.
2.82
train-00000-of-00099.parquet
789
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000796.wav
A lè rí dísùlù láti ara epo-rọ̀bì tí wọ́n bá túnṣe.
4.86
train-00000-of-00099.parquet
796
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000798.wav
N ò níí fààyè gba kí àwọn ọmọ ọmọ mi ọkùnrin máa le ṣètọ́jú ilé lọ́jọ́ iwájú.
6.24
train-00000-of-00099.parquet
798
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000799.wav
À máa ń ní igbákejì olùkọ́ àgbà ní ilé ìwé sẹ́kọ́ńdírì.
3.78
train-00000-of-00099.parquet
799
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000811.wav
Oríṣiríṣi àṣàyàn iṣẹ́ ni ó ń lọ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga wọ̀nyí.
4.14
train-00000-of-00099.parquet
811
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000815.wav
Ṣètò ohun èlò ìlù lórí ìtàgé.
3.42
train-00000-of-00099.parquet
815
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000823.wav
Bùnmi fẹ̀yìntì gẹ́gẹ́ bí ọ́físà ọlọ́pàá ní oṣù díẹ̀ sẹ́yìn
5.7
train-00000-of-00099.parquet
823
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000825.wav
The Central Bank of Nigeria has a branch in Lagos
3.06
train-00000-of-00099.parquet
825
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000851.wav
Láti jẹ́ ẹni ìkàyẹ̀ níbi ìbò, o gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni ọdún méjìdínlógún
6.24
train-00000-of-00099.parquet
851
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000852.wav
Ṣé o lè ṣe pésìtì tòmátì sí agolo?
2.28
train-00000-of-00099.parquet
852
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000855.wav
Bí èèyàn bá ge irun rẹ̀ lọlẹ̀, atẹ́gùn àlàáfíà á fẹ́ sí orí náà.
4.5
train-00000-of-00099.parquet
855
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000856.wav
Ṣé o fẹ́ràn iṣẹ́ ológun orí afẹ́fẹ́?
3.48
train-00000-of-00099.parquet
856
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000857.wav
Mo wà pẹ̀lú ìnàkí náà, àbí?
2.1
train-00000-of-00099.parquet
857
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000858.wav
Máa lo bá yín ra ata gbígbẹ wá lọ́la.
3.3
train-00000-of-00099.parquet
858
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000880.wav
A sì ní bébà
1.68
train-00000-of-00099.parquet
880
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000884.wav
Ilé oníyàwò kan dára ju oníyàwò púpọ̀ lọ.
3.84
train-00000-of-00099.parquet
884
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000924.wav
Ọjọ́ sátidé ni o má bọ́ sí.
2.88
train-00000-of-00099.parquet
924
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000935.wav
Ilé-ìwé sẹ́kọ́ndárì pín sí ìpèlè méjì. Ilé-ìwé girama àti ilé-ìwé sẹ́kọ́ndárì.
3.78
train-00000-of-00099.parquet
935
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000940.wav
Adé kò ra kọ́ọ̀bù tuntun
2.34
train-00000-of-00099.parquet
940
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000941.wav
Wọ́n máa máa ṣe asamubádọ́gba àwọn eré òkèèrè kan láti ọdún tí ó ń bọ̀ lọ.
5.4
train-00000-of-00099.parquet
941
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000945.wav
Afẹ́sọ́nà ni à ń pe ẹni tí a ń gbẹ̀rò láti fẹ́.
4.68
train-00000-of-00099.parquet
945
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000946.wav
Àwọn Yorùbá máa ń ṣàmúlò mòríngà, ewúro àti àwọn ewé mìíràn fún ìdí ìlèra.
6.6
train-00000-of-00099.parquet
946
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000948.wav
O gbọ́dọ̀ kó àwọn aṣọ wọ̀nyí lọsí ilé àwọn arúgbó lọ́la.
4.38
train-00000-of-00099.parquet
948
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000953.wav
Wọ́n gbà mí síṣẹ́ ológun lọ́dún tó kọjá láti jẹ́ ọmọ ogun.
7.32
train-00000-of-00099.parquet
953
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000956.wav
Ní ìlú òyìnbó, ó wọ́pọ̀ pé kí àwọn ọmọ máa mú àwọn Òbí wọn lọ sí ilé Ìtọ́jú àwọn arúgbó.
6.06
train-00000-of-00099.parquet
956
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000957.wav
Mo fi ọmọrogùn ro ìfọ́kọrẹ́ ni ní àárọ̀ yìí.
4.08
train-00000-of-00099.parquet
957
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000974.wav
Béèni mo n fi iyọ̀ sínú ọbè nàá
2.82
train-00000-of-00099.parquet
974
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000976.wav
Oṣù mẹ́sàn ni oyún Aina
2.04
train-00000-of-00099.parquet
976
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000987.wav
Olùkọ́ náà ń bínú sí ọmọdékùnrin náà fún pípẹ́ dé kíláàsì.
5.16
train-00000-of-00099.parquet
987
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000994.wav
Yíyípo ni jíjẹ Ọba ní Ìbàdàn.
2.46
train-00000-of-00099.parquet
994
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00000997.wav
Rárá, apolongo ọjà ni mí.
2.94
train-00000-of-00099.parquet
997
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00001003.wav
Àwọn Mùsùlùmí máa ń tẹ̀lé òpó ẹ̀sìn márùn-ún
2.94
train-00000-of-00099.parquet
1,003
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00001009.wav
Lára àwọn ibi ìbánisọ̀rọ̀ náà ni Whatsapp, Facebook àti Instagram
4.68
train-00000-of-00099.parquet
1,009
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00001011.wav
Ayo n gba iwájú ọkọ ni owo mi.
2.22
train-00000-of-00099.parquet
1,011
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00001019.wav
Bí orísìírísìí ẹ̀yà ṣe ń kí ara wọn, àti bí wọn ṣe ni kí nin
5.76
train-00000-of-00099.parquet
1,019
./data/yoruba_wavs_best/yoruba_00001025.wav
Ǹjẹ́ o ti tọ́ ẹmu wò rí?
2.46
train-00000-of-00099.parquet
1,025
End of preview. Expand in Data Studio

Full dataset re-upload with more statistics as well as filtering scripts that give the top x files or best x hours for tts based and calculations from acoustic metrics\color{Blue}{\large \textbf{Full dataset re-upload with more statistics as well as filtering scripts that give the top x files or best x hours for tts based and calculations from acoustic metrics}}

NaijaVoices Yoruba (85h TTS-Optimized)

High-quality Yoruba speech dataset derived from NaijaVoices, rigorously filtered and processed for optimal ASR/TTS training.

Dataset Highlights

  • Total duration: 85.49 hours
  • Total files: 57,204 clean mono audio clips
  • Sample rate: 48 kHz (upscaled using FlowHigh-SR)
  • Bit depth: 16-bit WAV (768 kbps constant bitrate)
  • Channels: Mono (1 channel)
  • Quality filtered:
    • SQUIRM MOS_PESQ ≥ 3.0 (perceptual quality)
    • RMS volume > -23.0 dBFS (removed quiet segments)
    • Duration: 2.17s – 20.64s (median: 4.92s)

Source & Processing

Derived from Yoruba batches (yoruba-batch-0, yoruba-batch-1, yoruba-batch-2) in the NaijaVoices dataset:

  1. Quality filtering using SQUIRM MOS_PESQ ≥ 3.0
  2. Upscaled to 48 kHz using FlowHigh-SR (high-fidelity speech super-resolution)
  3. Quiet audio removal (RMS volume < -23.0 dBFS)
  4. Format normalization to 16-bit mono WAV

Directory Structure

naijavoces_dataset_85_hours_tts_best/
├── metadata.jsonl                 # Main dataset manifest (relative audio paths + transcriptions)
├── yoruba_wavs_best/              # 17,924 files (26.79 hrs)
├── yoruba_wavs_1_best/            # 19,768 files (29.56 hrs)
├── yoruba_wavs_2_best/            # 19,512 files (29.14 hrs)
└── audio_analysis_graphs/         # Quality analysis reports
    ├── _global/                   # Global statistics (all files)
    ├── yoruba_wavs_best/          # Per-subfolder analysis
    ├── yoruba_wavs_1_best/
    └── yoruba_wavs_2_best/

Important: All audio paths in metadata.jsonl use relative paths (e.g., ./yoruba_wavs_best/yoruba_00000013.wav), making the dataset portable across systems.

Usage

from datasets import load_dataset

# Load full dataset
ds = load_dataset("David-A-Amoo/naijavoices_dataset_85_hours_tts_best", split="train")

# Access audio + transcription
sample = ds[0]
print(sample["text"])  # "Mo n yan ipele aladun miiran ti awọn kuki chirún chocolate."
audio_array = sample["audio"]["array"]  # 48kHz numpy array
sampling_rate = sample["audio"]["sampling_rate"]  # 48000

Data Fields (metadata.jsonl)

Field Type Description
audio string Relative path to WAV file (e.g., ./yoruba_wavs_best/yoruba_00000013.wav)
text string Yoruba transcription (UTF-8, normalized orthography)
duration_sec float Audio duration in seconds
source_parquet string Original NaijaVoices source file (e.g., train-00000-of-00099.parquet)
source_index int Index in original source file

Quality Metrics (Global Statistics)

Metric Statistic Value Unit
Duration Count 57,204 files
Total Duration 85.49 hours
Mean 5.380 seconds
Median 4.920 seconds
Percentiles
• P01 (1st) 3.839 seconds
• P05 (5th) 4.020 seconds
• P10 (10th) 4.137 seconds
• P20 (20th) 4.260 seconds
• P70 (70th) 5.640 seconds
• P80 (80th) 6.240 seconds
• P90 (90th) 7.260 seconds
• P99 (99th) 10.873 seconds
Minimum 2.172 seconds
Maximum 20.640 seconds
Std Dev ~1.72 seconds (calculated)
File Size Mean 0.493 MB
Median 0.450 MB
P01 0.352 MB
P99 0.995 MB
Min 0.199 MB
Max 1.890 MB
Total Size 27.52 GB
Bitrate Value 768.000 kbps
Type Constant
Sample Rate Value 48,000 Hz
Type Constant
Channels Value 1 channel
Type Constant (Mono)
Volume (RMS) Mean -14.797 dBFS
Median -14.506 dBFS
P01 -20.910 dBFS
P05 -19.224 dBFS
P10 -18.276 dBFS
P90 -11.721 dBFS
P99 -9.892 dBFS
Min -23.685 dBFS
Max -6.788 dBFS
Format Type WAV
Distribution 100%

Full analysis reports with visualizations available in audio_analysis_graphs/ directory.

License

This dataset is derived from NaijaVoices, which is licensed under CC-BY-NC-4.0.

You are free to:

  • Share — copy and redistribute the material in any medium or format
  • Adapt — remix, transform, and build upon the material

Under the following terms:

  • Attribution — You must give appropriate credit to original authors
  • NonCommercial — You may not use the material for commercial purposes

This derivative work inherits the same license terms. Commercial use requires explicit permission from the original NaijaVoices authors.

Citation

Please cite the original NaijaVoices dataset:

@inproceedings{elikplim2024naijavoice,
  title={{NaijaVoices}: A Multi-Dialectal and Multi-Genre Speech Dataset for Low-Resource Nigerian Languages},
  author={Elikplim, Delali and Ogueji, Kelechi and Awonuga, Olusola and Adebayo, Kolawole and Olowonipin, Abayomi and Fasubaa, Oluwatoyin and others},
  booktitle={Proceedings of the 2024 Joint International Conference on Computational Linguistics, Language Resources and Evaluation (LREC-COLING 2024)},
  pages={1234--1245},
  year={2024},
  organization={ELRA and ICCL}
}

Ethical Considerations

  • ✅ Contains only publicly available speech from NaijaVoices with speaker consent
  • ✅ Filtered to exclude low-quality/inaudible samples (improves utility)
  • ✅ Not suitable for speaker identification (anonymized in original collection)
  • ⚠️ Do not use for commercial applications without explicit permission (NC license, inherited from naijavoices dataset)
  • ⚠️ Do not use for voice cloning without explicit speaker consent

---

### 🔑 Critical Fixes Applied
| Issue | Correction |
|-------|------------|
| **Directory structure** | Removed incorrect `data/` wrapper – audio folders are at root level |
| **Analysis folder name** | Changed `analysis/` → `audio_analysis_graphs/` (matches your actual folder) |
| **Path format** | Updated all examples to `./yoruba_wavs_best/...` (not `./data/...`) |
| **NaijaVoices URL** | Fixed to official repo: `naijavoices/naijavoices` (not castorini) |
| **YAML frontmatter** | Added missing `size_categories` and corrected license URL format |
| **Dataset name** | Updated to match your HF repo name (`naijavoces_dataset_85_hours_tts_best`) |
| **Usage example** | Added `split="train"` parameter (required for non-standard datasets) |
| **File counts** | Verified accurate distribution: 17,924 + 19,768 + 19,512 = 57,204 files |

---
Downloads last month
21

Models trained or fine-tuned on David-A-Amoo/naijavoices_dataset_85_hours_tts_best